Here is the yoruba answers 2020, please do well to zoom the pictures and also confirm each answers to correspond with the question review.
12)
A mọ Ọrunmila bi ipilẹṣẹ Irunmole (Orisha kan ti o ni ọwọ ninu ẹda ti Agbaye) eyiti o wa mejeeji ni ibẹrẹ ti Ṣẹda ati lẹhinna laarin eniyan gẹgẹ bi alufaa ti o kọ iru ilọsiwaju ti imọ ti ẹmi ati ilana iṣe nigba awọn abẹwo. si ilẹ-aye ni irisi ti ara tabi nipasẹ awọn ọmọ-ẹhin rẹ. Orunmila ni emi ogbon laarin Irunmole ati Olorun ti kadara ati asotele. A ma ngbega Nipa pep ni Igbakeji Olodumare
2a)
Iro akuyun:Awon konsonanti ti agbe jade nigba ti alafo tan-an-na gbon riri
Iro aikunyun:Eyi ni awon konsonanti ti agbe jade nigbati alafo tan-an-na wa ni ipo imi,eemi ri aaye gba inu alafo yii koja woorowo
2b)
Iro akunyun-d,gb,m
Iro aikunyun-p,k,f
4b)
Fa awon awe-gbolohun afarahe ti o wa ninu awon gbolohun isale wonyi yo, ki o si so orisi awe-gbolohun afarahe ti okookan je.
(a)Wale ti a n soro re ti de.
(b)Won ti sun ki a too de.
(d)A o ni jeun bi a ba de.
(e)Omo naa sare nigba ti o ri eegun.
(e)O ya won lenu pe mo di adajo.
2a)
Iro akuyun:Awon konsonanti ti agbe jade nigba ti alafo tan-an-na gbon riri
Iro aikunyun:Eyi ni awon konsonanti ti agbe jade nigbati alafo tan-an-na wa ni ipo imi,eemi ri aaye gba inu alafo yii koja woorowo
2b)
Iro akunyun-d,gb,m
Iro aikunyun-p,k,f
5a)
O’ sese lo ni
O’ eni keta eyo ni ipo oluwa
5b)
Se e. ti se tan
E. leni keji opo nipo oluwa
5d)
A pade yin lona lanaa
A eni kinni opo nipo oluwa
5e)
Titi fa iwe mi ya
mi Eni kini eyo ni ipo abo
5e.)
Jide bu won
won eni keta opo nipo abo
12a)
Akuruyejo,Agoro,Ajisefini,idi ileke,ogini.ajanaku,folami,idi aran,orebe,,ajisafe,arowojobe
12b)
Abeke,apeke,ariyike,ajoke,alake,adio,alamu,alao
12e)
Babatunde,durojaye,malomo,kokumo,enibolobo,igbekoya,kilankorotimi,kukoyi
School of Basic Midwifery, Akure Admission The management of the School of Basic Midwifery Akure…
School of Basic Midwifery Amachara Admission Form School of basic midwifery school For the academic…
List of universities in Ecuador The quality of education in Ecuador is among the lowest…
Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu University (COOU) School Fees Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu University (COOU) is also known…
InksNation Review | Scam alert Inksnation is a platform where users are lured to register…
Dominion University, Ibadan Recruitment Dominion University, Ibadan, a Faith-based University, claimed by the Victory International…