YORUBA WAEC GCE ANSWERS 2020

YORUBA WAEC GCE ANSWERS 2020

*CHOOSE QUESTION 2A&B*

2a)

Iro akuyun:Awon konsonanti ti agbe jade nigba ti alafo tan-an-na gbon riri

Iro aikunyun:Eyi ni awon konsonanti ti agbe jade nigbati alafo tan-an-na wa ni ipo imi,eemi ri aaye gba inu alafo yii koja woorowo

2b)

Iro akunyun-d,gb,m

Iro aikunyun-p,k,f

(2)
TABULATE
ORO| IHUN SILEBU|IYE SILEBU
(a)
(i) Bae| Ba-e | 2
kf f
(ii) Waa|Wa-a|2
kf f
(iii)Suu|Su-u|2
kf f

(b)
(i) Kaabo|Ka-a-bo|3
kf f kf
(ii)Kuule| Ku-u-le|3
kf k kf
(iii) Boolu| Bo-o-lu|3
kf f k

(d)
(i)Aare|A-a-re|3
f f kf
(ii) Ooru|o-o-ru|3
f f kf
(iii) Oola|o-o-la|3
f f kf

(e)
(i) Panla|pa-n-la|3
kf n kf
(ii) Konko|Ko-n-ko|3
kf n kf
(iii) Kongbe|Ko-n-gbe|3
kf n kf

Cheers

Leave a Reply

error: Content is protected !!