WAEC UPDATES

WAEC Yoruba Questions and Answers 2020

WAEC Yoruba Questions and Answers 2020

NOTE That this post is basically a past question, the main question and answers will be posted here few hours to the exam, ensure to allow notification, join our telegram channel or more to get the answers when it drops

WAEC Yoruba Questions & Answers 2020
SECTION A: Aroko

1. (a) Ìdíje kan tí ó wáyé ni ilé-ẹ̀kọ́ mi.
(b) Ọ̀rẹ́ mi tí mo fẹ́ràn jù lọ.
(c) Ìsàlẹ̀ orọ̀ ní ẹ̀gbin.
(d) Ẹ̀sìn ti dòwò lórílẹ̀ èdè yìí.
(e) Ko lẹ́tà sí ọ̀rẹ́ ri tí ó wà ní ilẹ̀ òkèèèrè kí o sàlàyé akitiyan ìjoba lórí iná ẹ̀létíírìkì ní orílẹ̀-èdè rii.

2. sàlàyé ìhun ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wúnrẹ̀n wọ̀nyí kí o sì fi àppeere méjì méjì gbe ìdáhùn rẹ̀ lẹ́sẹ̀:
(a) àrànmọ́wájú;
(b) àrànmẹ́yìn:
(c) àrànmọ́ aláìfòró.

3. (a) Kí ni fáwẹ̀lì?
(b) Ṣe àpèjúwe ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fáwẹ̀lì wọ̀nyí:
[i], [Ԑ], [a], [o], [ũ], [ͻ̃].

4. (a) Da´ru´ku i`s?`ri´ ?`r?` ti a fala` si´ ni´nu´ ?`k?`?`kan a`w?n gbo´lo´hu`n w?`nyi´:
(i) E?ku`n pa eran.(ii) B?´la´ ri`n de´ ile´.
(ii) W?´n gba owo´ Ade´??la´.
(iii) O´ pupa fo`o`.
(iv) Aja´ gbe´ eegun.
(v) Mo fo aoo.
(b) Lo ?`k?`?`kan ?`r?` ti a fa`la` si´ ni ab?` (a) g?´g?´ bi´ ori´ ni´nu´ gbo´lo´hu`n a`ki´ye`si´ ala´t?num?´.

 

SECTION B: Litireso

6. Nínú ìtàn “Ìjàpá àti àwọn Ẹranko” ète wo ni Ìjàpá pa àti pé báwo ni àṣírí rẹ̀ ṣe tú?

7. Ṣalàyé ohun tí ifá so nipa Ògún.

8. se àlàyé kikún nipa bi Ọ̀jẹ́làdé ti o di ọ̀nì ṣe di ènìyàn padà.

9. Ṣàlàyé lẹ́kùnrẹ́rẹ́ ohun tí ó ṣokùnfà kíkó jáde ìyá Ọlánikẹ̀ẹ́ nílé ọkọ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì.

10. sàlàyé ìhùwàsí Ahun gẹ́gẹ́ bi akéwì ṣe fì yé wa nínú ewì náà.

11. sàlàyé bí Àbẹ̀ó ṣe ba ayé Àńwòó jẹ́.

SECTION C: ASA

12. Dárúku oríṣì oúnje mẹ́fà tí a ń fi erèé/ẹ̀wà se kí o sì sàlàyé bí a tì ń se méjì nínú won.

13. Dárúko mẹ́fà nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀de kí o sì sàlàyé sókí sókí lórí ọ̀kọ̀ọ̀kan.

NOTE That this post is basically a past question, the main question and answers will be posted here few hours to the exam, ensure to allow notification, join our telegram channel or more to get the answers when it drops

MyScholarshipBaze

I love surfing the web and providing great information for my readers. I am an Editor At Myscholarshipbaze.com

Recent Posts

African University of Science & Technology School Fees 2023

African University of Science & Technology School Fees 2023 African University of Science and Technology…

17 minutes ago

Facts about Ebira ethnic group

Facts about Ebira ethnic group Igbira, often spelled Igbirra or Ebira, are people who live…

6 hours ago

Caritas University School fees for 2023

Caritas University School fees for the 2023 academic session Caritas University management and Authorities have…

11 hours ago

American University of Nigeria School fees for 2023

The American University of Nigeria School Fees for the 2023 academic session The management of…

15 hours ago

AJAYI CROWTHER UNIVERSITY SCHOOL FEES 2023

AJAYI CROWTHER UNIVERSITY SCHOOL FEES 2023 The management had published the SCHEDULE OF  FEES FOR…

17 hours ago

Federal university of petroleum resources school fees for 2023

Federal University of petroleum resources school fees for the 2023 academic session The Authorities and…

20 hours ago