WAEC UPDATES

WAEC YORUBA ANSWERS 2021

WAEC YORUBA ANSWERS 2021

Here is the waec verified Yoruba answers 2021. Subscribe to get full answers.

Question 1d
*Aroko Lori igi Owo* (Igi Ope)

Igi ope je igi ti Olorun yo nu si pupo julo fun iwulo omo eniyan pelu iwulo fun eranko inu Igbo ni Pataki julo igi ope je igi ti a gbin ni ile Yoruba Pataki julo ni orile ede Naijiria, ati ile Afirika, ki awon oyinbo alawo fun fun to mu eso ope ti amo si eyin losi ilu oyinbo bi Burasili, Ile Larubawa, ile mexico, ile Amerika, ati awon ile oyinbo, ti ako le daruko tan aimoye egberun odun seyin ni igi ope ti wa ti alepe ni igi aba laiye

IGI OPE: Igi ope ama pe laiye gege bi omo eniyan se ma unpe laiye orisirisi igi ope ni owa ope miran ma un lo ogorun odun laiye tabi jubelo igi ope agbon maun lo to ogorin odun laiye tabi jubelo ti ope ba pe laiye tan ti igi ope naa ba ku awon eranko mi ran ma un fi inu igo igi ope se Ile eranko bi okete, okere, ejo, ekute, kokoro, bi ogoungo, oyin, ti otun ma wulo fun eranko ati eda eniyan

ERANKO: Eranko awon eranko pupo loma unje eyin gegebi ounje oojo won fun apere eranko bi okere, oya, okete, ati awon orisirisi eye ati awon eranko miran ti akole daruko won tan

AJE: Aje walara ope ti otiku ti ale fiwe iha aje yi ni won maunlo latifi yin ibon pelu eroja bi ahaya, etu, aje, won awaki daradara pelu opa ibon won ski aje naa daradara ki won to me yin ibon naa fun eranko tabi fipa oun koun

ORUKO ESO IGI OPE AMA JE: Eyin ninu eyin yi ni won to ma un yo epo pupa ti afi un se obe tabi se orisirisi unkan miran

EYIN KIKO: Okunrin loma un gun igi ope lati ko Eyin

BAWO: Bawo ni ibi ti won ma unko opolopo eyin ti won batiko si ibesini won ati mayo eyin kuro lara soo so okunrin ati obirin omode ati agbalagba loma unyo eyin kuro lara soo so

YIYO EYIN: Yiyo eyin kuro lara soo so

SOO SO: Soo so je ile ti eyin maun wa ni nure sugbon olewu pupo nitoripe soo so le gun eniyan ni owo tabi ese ki owo naa si ma se eje tabi ibi kibi ti oba ti gun eniyan lara awon elomiran tun maun lo soo so fun ogun lilo

EKU: Eku ni ibiti won ti maun se epo pupa ninu gorodomu ni unla ti eyin ba ti jinna tan won agun ninu koto ti won unpe ni eku ibe ni won ti mayo epo pupa loto, ekuro, iha, ikete ti won ma fiunje isu sise tabi isu yiyan

IGI OPE : Je igi ti o ma un so eso Pataki ti o bati dagba tan eso naa le wulo lorisi risi ona

EPO PUPA : Epo pupa je oun ti awa eda eniyan ni lo pupo ama un fi epo pupa se obe tabi lati fi din un kan jije tabi eroja fun ogun lilo

LATI ARA ESO EYIN: Lati ri awon un kan mi ran ti owulo fun eda eniyan

Lati ara eso eyin ni ati ri

IHA: Iha je oun ti won ma un fi da ina tabi tan ina

OGUNSO: Bakan naa won ma un fi ogunso tan ina tabi fida ina lati se oun jije tabi mimu

EKURO: Ekuro je eso lati inu eyin ti wonka lati ara igi ope ti won ba pa ekuro tan won ma unyo esan lati ara ekuro won si ma un fi esan Dana

ADI: Won ma un yo adi Latin ara ekuro won ma unlo adi fun ipara tabi Latin fi wo opolopo aisan

OSE DUDU: Lati ara eso eyin ti a unpe ni ekuro ni won ti ma un se ose dudu fun wiwe tabi po eroja egbo igi mo Lati fi wo aisan kekere tabi ni unla San

IGBALE: Ewe ori igi ope ni won fi un se igbale tabi owo ti afi ungbale

EFON: Efon ti owa Lara ewe ope ni won fi un hun apere ati orisi risi unkan

ORORO TABI ADIAGBON : Ororo tabi adiagbon wa Lara ekuro oun ni won unlo fun ipara tabi Lati fi wo opolopo aisan nla tabi kekere

IMON: Imon je ewe ope ti won ma unlo lati fiko ile keke bi ahere, atibaba, tiama unlo ni laiye ojoun ni unkan bi odun 1850, odun 1950, odun 1960 ati odun 1970, ni igbayen ni awa ni ilewe alakobere imon ni ama unfiko kilasi ati atibaba ti won ti awon eniyan pataki ti maunjoko ti won baunse ayeye awon eniyan bi Oba ilu, ijoye, olori ile eko, ati awon oluko ile iwe olori esin bi esin islam, esin kirisiteni, imon yi naa ni won tun maunlo fun opolopo ere idaraya
wo oremi Olorun Oba da unkan lorisirisi fun anunfani awa eda eniyan ti won ba fi igi ope we eniyan oma dara pupo toripe kosi eya ara ope ti kowulo ki Olorun Oba Olojo oni jeki aiye wa dara ju aiye igi ope lo.

MyScholarshipBaze

I love surfing the web and providing great information for my readers. I am an Editor At Myscholarshipbaze.com

Recent Posts

Start your New financial Saving Plan for year 2023

Start your New financial Saving Plan for the year 2023 We have 365 days, 53…

3 hours ago

INTERNSHIP APPLICATION AT ONDO STATE HOSPITAL

APPLICATION FOR THE UNIVERSITY OF MEDICAL SCIENCES, ONDO CITY IS ON Requirements: 1. CV: This…

8 hours ago

Federal government recruitment | Application form for all ministries.

Federal government recruitment application form for all ministries The federal government has come up with…

11 hours ago

Guides on how to apply and get a scholarship

Step-by-step guides on how to apply and get a scholarship In my previous post, I…

14 hours ago

NIGER STATE SCHOLARSHIP 2022

NIGER STATE SCHOLARSHIP 2022 The Niger State Government has created an opportunity for its indigene…

19 hours ago

SCHOOL OF POST BASIC NURSING, OCCUPATIONAL HEALTH UCH IBADAN.

SCHOOL OF POST BASIC NURSING, OCCUPATIONAL HEALTH UCH IBADAN. The School of Post Basic Nursing,…

23 hours ago