Here is neco Yoruba answers for 2021, share with your friends.
1. (a)Kọ àròkọ tí kò dín ní 300 ẹyọ ọ̀rọ̀ lórí orí-ọ̀rọ̀ kan ṣoṣo tí o bá yàn.
Ìṣẹ̀lẹ̀ búburú kan tí n kò lè gbàgbé láéláé.
Iṣẹ́ lòògùn ìṣẹ́.
(d) Ọjà kan ní agbègbè mi.
Ìwé kíkà dára ju iṣẹ́ kíkọ́ lọ.
(e) Kọ lẹ́tà sí ẹ̀gbọ́n rẹ tí ó wà ní ilẹ̀ òkèèrè láti ṣe àlàyé ìgbáradì tí o ń ṣe fún ìdánwò àṣekágbá rẹ kí o sì béèrè ìrànwọ́ nípa àwọn ohun tí o nílò.
2. Mú márùn-ún nínú àwọn ọ̀nà ìṣẹnupè kọ́ńsónáǹtì Yorùbá kí o sì ṣ̀alàyé ọ̀kọ̀ọ̀kàn wọn.
3.
SECTION B: Aroko
4. sàlàyé ìhun ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wúnrẹ̀n wọ̀nyí kí o sì fi àppeere méjì méjì gbe ìdáhùn rẹ̀ lẹ́sẹ̀:(a) àrànmọ́wájú;
(b) àrànmẹ́yìn:
(d) àrànmọ́ aláìfòró.
5. (a) Kí ni fáwẹ̀lì?
(b) Ṣe àpèjúwe ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fáwẹ̀lì wọ̀nyí:
[i], [Ԑ], [a], [o], [ũ], [ͻ̃].
6. (a) Da´ru´ku i`s?ri´ ?`r? ti a fala` si´ ni´nu´ ?k??`kan a`w?n gbo´lo´hu`n w?`nyi´:
(i) E?ku`n pa eran.
(ii) B?´la´ ri`n de´ ile´.
(iii) W?´n gba owo´ Ade´??la´.
(iv) O´ pupa fo`o`.
(v) Aja´ gbe´ eegun.
(vi) Mo fo aoo.
(b) Lo ?k??kan ?`r? ti a fa`la` si´ ni ab?` (
(c) g?´g?´ bi´ ori´ ni´nu´ gbo´lo´hu`n a`ki´ye`si´ ala´t?num?´.
6.
SECTION C: Litireso
How To Make Your Relationship work Relationship Back Bones: * Love * Trust * Commitment…
Afe Babalola University (ABUAD) School fees 2023 AFE Babalola University is a private institution commissioned…
NIGER DELTA UNIVERSITY SCHOOL FEES FOR THE 2023 ACADEMIC SESSION NIGER DELTA UNIVERSITY SCHOOL FEES…
OSUN STATE UNIVERSITY SCHOOL FEES FOR THE 2023/2024 ACADEMIC SESSION OSUN State University School Fees…
Fountain University Osogbo school fees for the 2023/2024 academic session The management and Board of…
Cross River University of Technology school fees for the 2023/2024 academic session This is to…